Àwọn Ọba Keji 23:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Neko sì fi Eliakimu, ọmọ Josaya, jọba dípò rẹ̀, ṣugbọn ó yí orúkọ rẹ̀ pada sí Jehoiakimu. Neko mú Jehoahasi lọ sí Ijipti, ibẹ̀ ni ó sì kú sí.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:24-36