Àwọn Ọba Keji 23:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Neko ọba Ijipti mú Jehoahasi ní ìgbèkùn ní Ribila ní ilẹ̀ Hamati, kí ó má baà jọba lórí Jerusalẹmu mọ́. Ó sì mú kí Juda san ọgọrun-un (100) ìwọ̀n talẹnti fadaka ati ìwọ̀n talẹnti wúrà kan bí ìṣákọ́lẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:29-35