Àwọn Ọba Keji 23:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí ogun rẹ̀ gbé òkú rẹ̀ sinu kẹ̀kẹ́ ogun kan láti Megido wọn gbé e wá sí Jerusalẹmu, wọ́n sì sin ín sinu ibojì rẹ̀.Àwọn eniyan Juda sì fi òróró yan Jehoahasi ọmọ rẹ̀ ní ọba.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:26-37