Àwọn Ọba Keji 23:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹtalelogun ni Jehoahasi nígbà tí ó jọba ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún oṣù mẹta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hamutali, ọmọ Jeremaya, ará Libina.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:21-33