Àwọn Ọba Keji 23:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò tí Josaya jọba ni Neko, ọba Ijipti kó ogun rẹ̀ wá sí etí odò Yufurate láti ran ọba Asiria lọ́wọ́. Josaya pinnu láti dá ogun Ijipti pada ní Megido, ṣugbọn ó kú lójú ogun náà.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:24-35