Àwọn Ọba Keji 23:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo àwọn ìlú Israẹli ni Josaya ti wó àwọn ilé oriṣa tí àwọn ọba Israẹli kọ́ tí ó bí OLUWA ninu. Bí ó ti ṣe pẹpẹ ìrúbọ tí ó wà ní Bẹtẹli ni ó ṣe àwọn pẹpẹ ìrúbọ náà.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:18-26