Àwọn Ọba Keji 23:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pa gbogbo àwọn alufaa ibi ìrúbọ lórí pẹpẹ ìrúbọ wọn, ó sì jó egungun eniyan lórí gbogbo àwọn pẹpẹ ìrúbọ náà. Lẹ́yìn náà, ó pada sí Jerusalẹmu.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:10-29