Àwọn Ọba Keji 23:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Josaya bá pàṣẹ pé kí wọ́n fi sílẹ̀ bí ó ti wà, kí wọ́n má ṣe kó egungun rẹ̀.Nítorí náà, wọn kò kó egungun rẹ̀ ati egungun wolii tí ó wá láti Samaria.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:9-22