Àwọn Ọba Keji 21:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún àwọn ilé oriṣa tí Hesekaya, baba rẹ̀ ti parun kọ́, ó kọ́ pẹpẹ ìrúbọ fún oriṣa Baali, ó sì gbẹ́ ère oriṣa Aṣera, bí Ahabu, ọba Israẹli, ti gbẹ́ ẹ. Ó sì ń bọ àwọn ìràwọ̀.

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:1-4