Àwọn Ọba Keji 21:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ pẹpẹ ìrúbọ oriṣa sinu ilé OLUWA, níbi tí OLUWA ti pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli láti máa sin òun.

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:1-6