Àwọn Ọba Keji 21:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Manase ṣe nǹkan tí ó burú lójú OLUWA nítorí pé ó tẹ̀lé ìwà ìríra àwọn eniyan ilẹ̀ náà, tí OLUWA lé jáde kúrò níwájú àwọn ọmọ Israẹli.

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:1-4