Àwọn Ọba Keji 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ ọdún mejila ni Manase nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún marundinlọgọta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hefisiba.

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:1-3