Àwọn Ọba Keji 20:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Aisaya gbadura sí OLUWA, OLUWA sì mú kí òjìji pada sẹ́yìn ní ẹsẹ̀ mẹ́wàá lára àtẹ̀gùn ilé tí ọba Ahasi ṣe.

Àwọn Ọba Keji 20

Àwọn Ọba Keji 20:3-17