Àwọn Ọba Keji 20:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya dáhùn pé, “Ó rọrùn fún òjìji láti lọ siwaju ní ẹsẹ̀ mẹ́wàá, kí ó pada sẹ́yìn ni mo fẹ́.”

Àwọn Ọba Keji 20

Àwọn Ọba Keji 20:1-12