Àwọn Ọba Keji 20:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan náà ni Merodaki Baladani, ọmọ Baladani, ọba Babiloni, fi ìwé ati ẹ̀bùn ranṣẹ sí Hesekaya nítorí ó gbọ́ pé Hesekaya ń ṣe àìsàn.

Àwọn Ọba Keji 20

Àwọn Ọba Keji 20:6-18