Àwọn Ọba Keji 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Rabuṣake gbọ́ pé ọba Asiria ti kúrò ní Lakiṣi láti lọ jagun ní Libina, ó sì lọ sibẹ láti lọ rí i.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:6-9