Àwọn Ọba Keji 19:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọba Asiria gbọ́ pé Tirihaka, ọba Etiopia, ń kó ogun rẹ̀ bọ̀ láti bá òun jagun, ó ranṣẹ sí Hesekaya, ọba Juda, ó ní kí wọ́n sọ fún un pé,

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:8-10