Àwọn Ọba Keji 19:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní òun óo fi ẹ̀mí kan sinu rẹ̀, tí yóo mú kí ó sá pada sí ilẹ̀ rẹ̀ nígbà tí ó bá gbọ́ ìròyìn kan, òun óo sì jẹ́ kí wọ́n pa á nígbà tí ó bá dé ilẹ̀ rẹ̀.”

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:5-15