Àwọn Ọba Keji 19:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ti dáná sun àwọn ọlọrun wọn; ṣugbọn wọn kì í ṣe Ọlọrun tòótọ́, ère lásán tí a fi igi ati òkúta gbẹ́ ni wọ́n, iṣẹ́ ọwọ́ ọmọ eniyan.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:11-25