Àwọn Ọba Keji 19:17 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, àwa mọ̀ pé ní òtítọ́ ni ọba Asiria ti pa ọpọlọpọ àwọn orílẹ̀-èdè run, ó sì ti sọ ilẹ̀ wọn di aṣálẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:12-27