Àwọn Ọba Keji 19:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, bojú wo ohun tí ń ṣẹlẹ̀ sí wa; kí o sì gbọ́ bí Senakeribu ti ń sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn sí ìwọ Ọlọrun alààyè.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:9-25