Àwọn Ọba Keji 18:7 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wà pẹlu rẹ̀, ó sì ń ṣe àṣeyọrí ninu gbogbo ohun tí ó ń ṣe. Ó gba ara rẹ̀ lọ́wọ́ ọba Asiria, ó di òmìnira, ó kọ̀ kò sìn ín mọ́.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:1-11