Àwọn Ọba Keji 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣẹgun àwọn ará Filistia, títí dé ìlú Gasa ati agbègbè tí ó yí i ká, ati ilé ìṣọ́ wọn, ati ìlú olódi wọn.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:1-13