Àwọn Ọba Keji 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó jẹ́ olóòótọ́ sí OLUWA, kò yapa kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, ṣugbọn ó fi tọkàntọkàn pa àwọn òfin tí OLUWA fún Mose mọ́.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:1-15