Àwọn Ọba Keji 18:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà wo ni ọ̀kan ninu àwọn ọlọrun orílẹ̀-èdè wọnyi gba orílẹ̀-èdè wọn lọ́wọ́ ọba Asiria rí, tí OLUWA yóo fi gba Jerusalẹmu lọ́wọ́ mi?”

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:34-37