Àwọn Ọba Keji 18:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbo ni ọlọrun Hamati ati ti Aripadi wà? Níbo ni àwọn ọlọrun Sefafaimu, ati ti Hena ati ti Ifa wà? Ṣé wọ́n gba Samaria lọ́wọ́ mi?

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:30-37