Àwọn Ọba Keji 18:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan náà dákẹ́ jẹ́ẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọba Hesekaya ti pàṣẹ fún wọn, wọn kò sọ ọ̀rọ̀ kankan.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:34-37