Àwọn Ọba Keji 18:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò lè ṣẹgun ẹni tí ó kéré jùlọ ninu àwọn ọ̀gágun ọba Asiria, sibẹ o rò pé àwọn kẹ̀kẹ́ ogun ati àwọn ẹlẹ́ṣin ọba Ijipti yóo ràn ọ́ lọ́wọ́.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:18-33