Àwọn Ọba Keji 18:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé o rò pé lásán ni mo wá láti pa ilẹ̀ yìí run, láìsí ìrànlọ́wọ́ OLUWA? OLUWA fúnra rẹ̀ ni ó sọ fún mi pé kí n wá pa ilẹ̀ yìí run.”

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:22-27