Àwọn Ọba Keji 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, ẹ wá ṣe àdéhùn pẹlu ọba Asiria, oluwa mi. N óo fun yín ní ẹgbaa (2,000) ẹṣin bí ẹ bá lè rí ẹgbaa (2,000) eniyan tí yóo gùn wọ́n.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:19-33