Àwọn Ọba Keji 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹta tí Hoṣea, ọmọ Ela, jọba ní Israẹli ni Hesekaya, ọmọ Ahasi jọba ní Juda.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:1-4