Àwọn Ọba Keji 17:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan ilẹ̀ náà sin OLUWA, ṣugbọn wọ́n ń bọ àwọn ère tí wọ́n gbẹ́ pẹlu. Àwọn ọmọ ati àwọn ọmọ ọmọ wọn sì ń ṣe bẹ́ẹ̀ títí di òní olónìí.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:32-41