Àwọn Ọba Keji 18:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni nígbà tí ó jọba, ó sì jọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkandinlọgbọn. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Abi, ọmọ Sakaraya.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:1-7