Àwọn Ọba Keji 17:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan náà bẹ̀rù OLUWA pẹlu, wọ́n sì yan oniruuru eniyan lára wọn, láti máa ṣe alufaa níbi àwọn pẹpẹ oriṣa gíga, láti máa bá wọn rúbọ níbẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:30-40