Àwọn Ọba Keji 17:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń sin OLUWA, ṣugbọn wọ́n tún ń bọ àwọn oriṣa tí wọn ń bọ tẹ́lẹ̀ ní orílẹ̀-èdè tí olukuluku wọ́n ti wá.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:27-41