Àwọn Ọba Keji 17:31 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn ará Afa gbẹ́ ère oriṣa Nibihasi ati Tataki, àwọn ará Sefafaimu sì ń sun ọmọ wọn ninu iná fún Adirameleki ati Anameleki, àwọn oriṣa wọn.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:21-41