Àwọn Ọba Keji 16:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasi kó fadaka ati wúrà tí ó wà ninu ilé OLUWA, ati tinú àwọn ilé ìṣúra tí ó wà ní ààfin jọ, ó kó o ranṣẹ sí ọba Asiria.

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:1-9