Àwọn Ọba Keji 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasi ranṣẹ lọ bá Tigilati Pileseri, ọba Asiria, ó ní, “Iranṣẹ ati ọmọ rẹ ni mo jẹ́, nítorí náà, jọ̀wọ́ wá gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọba Siria ati ti Israẹli tí wọ́n gbógun tì mí.”

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:3-9