Àwọn Ọba Keji 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan náà ni ọba Edomu gba Elati pada, ó sì lé àwọn ará Juda tí wọn ń gbé ibẹ̀, àwọn ará Edomu sì ń gbé ibẹ̀ títí di òní olónìí.

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:1-13