Àwọn Ọba Keji 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Resini, ọba Siria, ati Peka, ọba Israẹli, gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n sì dó ti Ahasi, ṣugbọn wọn kò lè ṣẹgun rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:1-6