Àwọn Ọba Keji 16:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Asiria gbọ́ ẹ̀bẹ̀ rẹ̀, ó sì gbógun ti Damasku, ó ṣẹgun rẹ̀, ó pa Resini ọba, ó sì kó gbogbo àwọn eniyan ìlú náà lẹ́rú lọ sí Kiri.

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:1-10