Àwọn Ọba Keji 15:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA; ó sì tẹ̀lé ìwà ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu, ọmọ Nebati, tí ó mú Israẹli dẹ́ṣẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:20-34