Àwọn Ọba Keji 15:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di aadọta ọdún tí Asaraya jọba ní Juda, ni Pekahaya, ọmọ Menahemu jọba lórí Israẹli, ní Samaria, ó sì wà lórí oyè fún ọdún meji.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:15-29