Àwọn Ọba Keji 15:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Peka, ọmọ Remalaya, olórí ogun rẹ̀, pẹlu aadọta ọmọ ogun Gileadi dìtẹ̀ mọ́ ọn, wọ́n sì pa á ní Samaria, ninu ilé tí a mọ odi tí ó lágbára yíká, tí ó wà ninu ààfin rẹ̀, Peka sì jọba dípò rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:15-26