Àwọn Ọba Keji 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹrindinlogun ni nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mejilelaadọta. Jekolaya ará Jerusalẹmu ni ìyá rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:1-8