Àwọn Ọba Keji 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹtadinlọgbọn tí Jeroboamu jọba ní Israẹli ni Asaraya ọmọ Amasaya, jọba ní Juda.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:1-4