Àwọn Ọba Keji 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun tí ó dára lójú OLUWA nítorí pé ó tẹ̀lé ọ̀nà Amasaya, baba rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:1-4