Àwọn Ọba Keji 15:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA títí di ọjọ́ ikú rẹ̀, nítorí pé ó tẹ̀lé ọ̀nà Jeroboamu ọba, ọmọ Nebati, tí ó mú Israẹli dẹ́ṣẹ̀ títí di ọjọ́ ikú rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:17-21