Àwọn Ọba Keji 15:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Pulu, tí à ń pè ní Tigilati Pileseri, ọba Asiria, gbógun ti ilẹ̀ Israẹli; kí ó baà lè ran Menahemu lọ́wọ́ láti fi ìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀, Menahemu fún un ní ẹgbẹrun (1,000) talẹnti owó fadaka.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:18-27