Àwọn Ọba Keji 15:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kọkandinlogoji tí Asaraya jọba ní Juda, ni Menahemu, ọmọ Gadi, jọba lórí Israẹli ní Samaria, ó sì wà lórí oyè fún ọdún mẹ́wàá.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:16-26